| [00:35.65] |
Iwa lewa omo eniyan, ko ba dakun toju iwa e |
| [00:45.78] |
Iwa lewa omo eniyan, ko ba dakun toju iwa e |
| [01:05.03] |
Iwa omo ni omo se ki n gbe |
| [01:12.49] |
E to ju e da da |
| [01:20.05] |
Iwa to ni ba dun, bami to ju e da da (da da) |
| [01:34.96] |
Iwa yi lo soro |
| [01:40.91] |
Lo se oun gbogbo ni mere mere banta |
| [01:45.58] |
N ba to ju e |
| [01:54.67] |
Iwa ni o ku oniwa ti o ba ti si anybody mo |
| [02:05.19] |
Iwa se pataki (pataki) |
| [02:14.42] |
A de le ba eni won ko n le |
| [02:17.41] |
E kole bi iwa eni ni |
| [02:22.22] |
Oniwa lo ni wa o |
| [02:28.19] |
Iwa omo ni mu omo so ki ngbe |
| [02:34.46] |
O ba dakun to ju e da da |
| [02:36.12] |
Iwa lewa omo eniyan, o ba dakun to ju iwa e |
| [02:41.63] |
Iwa lewa omo eniyan, o ba dakun to ju iwa e |
| [03:18.25] |
Ara banbi jaye oba |
| [03:20.30] |
Sope ijo ti ya fun orogbo |
| [03:26.51] |
Ara banbi jaye oba |
| [03:29.64] |
Sope ijo ti ya fun orogbo |
| [03:36.70] |
E ki olukosun ayana ina |
| [03:38.94] |
Sango ijo ti ya fun orogbo |
| [03:42.72] |
Afi ni fun jo bomo loju oko oya |
| [03:45.77] |
Sango ijo ti ya fun orogbo |
| [03:50.71] |
Ko jeun ajanaku ma fi iyo si |
| [03:52.93] |
Sango ijo ti ya fun orogbo |
| [03:57.02] |
E fufu lele ya gi mo aya apata |
| [03:59.83] |
Sango ijo ti ya fun orogbo |
| [04:03.71] |
Bi o wo odo ariwo ata |
| [04:06.54] |
Sango ijo ti ya fun orogbo |
| [04:11.48] |
Bi o gun oke odo ariwo ata |
| [04:13.20] |
Sango ijo ti ya fun orogbo |
| [04:17.59] |
Ko fese mejeji damiru oko oya |
| [04:20.38] |
Sango ijo ti ya fun orogbo |
| [04:24.45] |
Awa na ti ri oba koso |
| [04:27.55] |
Sango ijo ti ya fun orogbo |
| [04:31.69] |
E ki olukosun ayana ina |
| [04:34.44] |
Sango ijo ti ya fun orogbo |
| [04:38.71] |
E ba mi ki olukoso ayana ina |
| [04:40.69] |
Sango ijo ti ya fun orogbo |
| [04:43.65] |
Ara banbi jaye oba |
| [04:45.22] |
Sango ijo ti ya fun orogbo |
| [04:48.02] |
Ara banbi jaye oba |
| [04:50.34] |
Sango ijo ti ya fun orogbo |
| [04:55.78] |
|