Iwa lewa omo eniyan, ko ba dakun toju iwa e Iwa lewa omo eniyan, ko ba dakun toju iwa e Iwa omo ni omo se ki n gbe E to ju e da da Iwa to ni ba dun, bami to ju e da da (da da) Iwa yi lo soro Lo se oun gbogbo ni mere mere banta N ba to ju e Iwa ni o ku oniwa ti o ba ti si anybody mo Iwa se pataki (pataki) A de le ba eni won ko n le E kole bi iwa eni ni Oniwa lo ni wa o Iwa omo ni mu omo so ki ngbe O ba dakun to ju e da da Iwa lewa omo eniyan, o ba dakun to ju iwa e Iwa lewa omo eniyan, o ba dakun to ju iwa e Ara banbi jaye oba Sope ijo ti ya fun orogbo Ara banbi jaye oba Sope ijo ti ya fun orogbo E ki olukosun ayana ina Sango ijo ti ya fun orogbo Afi ni fun jo bomo loju oko oya Sango ijo ti ya fun orogbo Ko jeun ajanaku ma fi iyo si Sango ijo ti ya fun orogbo E fufu lele ya gi mo aya apata Sango ijo ti ya fun orogbo Bi o wo odo ariwo ata Sango ijo ti ya fun orogbo Bi o gun oke odo ariwo ata Sango ijo ti ya fun orogbo Ko fese mejeji damiru oko oya Sango ijo ti ya fun orogbo Awa na ti ri oba koso Sango ijo ti ya fun orogbo E ki olukosun ayana ina Sango ijo ti ya fun orogbo E ba mi ki olukoso ayana ina Sango ijo ti ya fun orogbo Ara banbi jaye oba Sango ijo ti ya fun orogbo Ara banbi jaye oba Sango ijo ti ya fun orogbo