Aye Ole

Aye Ole Lyrics

Song Aye Ole
Artist INFINITY
Album Heart And Soul Of Africa Vol, 55
Download Image LRC TXT
[00:12.15] Omo eniyan
[00:14.42] F'eti si
[00:16.66] Oro agba, bi o she l'owuro
[00:19.30] A she lowo ale
[00:23.59] Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d'opin
[00:29.05] Aimola eda lo mu eda saniyan ra
[00:34.38] Olorun ti seleri, oro baba ko ni ye
[00:39.19] Aini gbaggbao lo mu eda raropin
[00:45.15] Bi okun n fo
[00:46.94] Ti osa n sa
[00:48.04] Otito wa laaye
[00:50.84] Igbabo ni orisun ohun gbogbo
[00:55.44] Oh hu hu hu
[00:57.08] Aye yi ko male
[01:01.44] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
[01:06.01] Oh hu hu hu
[01:07.77] Aye yi ko male o
[01:12.32] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
[01:17.23] Hu hu hu
[01:18.85] Aye yi ko male
[01:23.26] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
[01:27.57] Oh hu hu hu
[01:29.19] Aye yi ko male o
[01:33.88] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
[01:38.72] Oni suuru, ape koto je, koni jebaje
[01:44.82] Ai mani suuru lo n mu are eni bo wa debi
[01:49.98] F'oju re womi ore, k'Oluwa le foju re wo e
[01:54.98] Abiku ti d'abiye ninu aye mi
[02:00.90] Oni suuru, ape koto je, koni jebaje
[02:06.30] Ai mani suuru lo n mu are eni bo wa debi
[02:11.56] F'oju re womi ore, k'Oluwa le foju re wo e
[02:16.83] Abiku ti d'abiye ninu aye mi
[02:22.27] Oh hu hu hu
[02:24.12] Aye yi ko male
[02:28.35] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
[02:33.16] Oh hu hu hu
[02:34.48] Aye yi ko male
[02:38.98] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
[02:43.66] Hu hu hu
[02:45.67] Aye yi ko male
[02:49.76] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
[02:54.62] Hu hu hu
[02:56.21] Aye yi ko male o
[03:00.45] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
[03:05.44] Ha ha ha
[03:08.08] Aye re ko ma ni le
[03:10.85] Ha ha ha
[03:12.89] To ba ba Olorun rin, o sho ri re
[03:16.22] Ha ha ha
[03:17.88] Aye re ko ma ni le
[03:21.63] Ha ha ha
[03:23.68] To ba ba Olorun rin, o sho ri re
[03:27.25] Ha ha ha
[03:29.23] Aye re ko ma ni le
[03:32.47] Ha ha ha
[03:34.77] To ba ba Olorun rin, o sho ri re
[03:38.05] Ha ha ha
[03:40.16] Aye re ko ma ni le
[03:43.16] Ha ha ha
[03:45.25] To ba ba Olorun rin, o sho ri re
[03:49.26] Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d'opin
[03:53.12]
Aye Ole Lyrics
YouTube Results (More on YouTube)