[00:12.15] Omo eniyan [00:14.42] F'eti si [00:16.66] Oro agba, bi o she l'owuro [00:19.30] A she lowo ale [00:23.59] Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d'opin [00:29.05] Aimola eda lo mu eda saniyan ra [00:34.38] Olorun ti seleri, oro baba ko ni ye [00:39.19] Aini gbaggbao lo mu eda raropin [00:45.15] Bi okun n fo [00:46.94] Ti osa n sa [00:48.04] Otito wa laaye [00:50.84] Igbabo ni orisun ohun gbogbo [00:55.44] Oh hu hu hu [00:57.08] Aye yi ko male [01:01.44] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole [01:06.01] Oh hu hu hu [01:07.77] Aye yi ko male o [01:12.32] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole [01:17.23] Hu hu hu [01:18.85] Aye yi ko male [01:23.26] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole [01:27.57] Oh hu hu hu [01:29.19] Aye yi ko male o [01:33.88] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole [01:38.72] Oni suuru, ape koto je, koni jebaje [01:44.82] Ai mani suuru lo n mu are eni bo wa debi [01:49.98] F'oju re womi ore, k'Oluwa le foju re wo e [01:54.98] Abiku ti d'abiye ninu aye mi [02:00.90] Oni suuru, ape koto je, koni jebaje [02:06.30] Ai mani suuru lo n mu are eni bo wa debi [02:11.56] F'oju re womi ore, k'Oluwa le foju re wo e [02:16.83] Abiku ti d'abiye ninu aye mi [02:22.27] Oh hu hu hu [02:24.12] Aye yi ko male [02:28.35] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole [02:33.16] Oh hu hu hu [02:34.48] Aye yi ko male [02:38.98] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole [02:43.66] Hu hu hu [02:45.67] Aye yi ko male [02:49.76] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole [02:54.62] Hu hu hu [02:56.21] Aye yi ko male o [03:00.45] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole [03:05.44] Ha ha ha [03:08.08] Aye re ko ma ni le [03:10.85] Ha ha ha [03:12.89] To ba ba Olorun rin, o sho ri re [03:16.22] Ha ha ha [03:17.88] Aye re ko ma ni le [03:21.63] Ha ha ha [03:23.68] To ba ba Olorun rin, o sho ri re [03:27.25] Ha ha ha [03:29.23] Aye re ko ma ni le [03:32.47] Ha ha ha [03:34.77] To ba ba Olorun rin, o sho ri re [03:38.05] Ha ha ha [03:40.16] Aye re ko ma ni le [03:43.16] Ha ha ha [03:45.25] To ba ba Olorun rin, o sho ri re [03:49.26] Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d'opin [03:53.12]