| Song | Alasela |
| Artist | Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band |
| Album | Atunluto |
| Download | Image LRC TXT |
| [00:15.46] | Bí mo bá ti r'éni mi, inú mi á dùn, ara mi á yá gágá |
| [00:23.41] | Ma r'wérín ayò, ma r'érín ìdùnnú, ma k'ọrin tuntun |
| [00:28.37] | Bí mo bá ti r'ẹ'ni mi, inú mi á dùn dé lẹ', ara mi á yá gágá |
| [00:36.33] | Ma j'íjó ayò, ma r'érín ìdùnnú |
| [00:41.48] | Jomijòkè ọlọ'wó-aró, ẹni mi àtàtà, ọjó ti mọ' |
| [00:46.31] | Ojú ayé ti là, gbé'ra ko pàdé mi lóde |
| [00:51.44] | Òfaragbìjà, alápá-ajé, aya mi àtàtà, ojú ti mọ' |
| [00:56.13] | Ọ'nà ọ'tun ti là, bóóde jàre |
| [01:00.52] | Wá ká lọ s'ójà ìdẹ'ra, ká mú 're bò wálé |
| [01:06.07] | Ọjọ' òní ọjó aláselà mà ló jẹ' |
| [01:10.36] | Wá ká lọ s'ókè ìdùnnú, ká m'áyò bò wá lé |
| [01:16.36] | Ọjó òní ọjọ' olóyin |
| [01:20.71] | Jomijòkè ọlówó-aró, ẹni mi àtàtà, ọjọ' ti mó |
| [01:25.58] | Ojú ayé ti là, m'áṣọ wò pàdé mi lóde |
| [01:30.43] | Òfaragbìjà, alápá-ajé, aya mi àtàtà, ojú ti mó |
| [01:35.09] | Ònà ọ'tun ti là, bóóde jàre |
| [01:40.35] | |
| [01:59.84] | Wá ká lọ s'ódò ìségun, ká f'àwòn kó're |
| [02:05.43] | Ọjọ' òní ọjọ' aláṣelà mà ló jẹ' |
| [02:09.47] | Wá ká lọ s'ọ'dọ' àgbà, k'ón súre fún wa |
| [02:15.29] | Ọwó àwa t'olúborí ni |
| [02:20.01] | Jomijòkè ọlọ'wọ'-aró, ẹni mi àtàtà, ọjọ' ti mọ' |
| [02:24.42] | Ojú ayé ti là, múra ko pàdé mi lóde |
| [02:29.82] | Òfaragbìjà, alápá-ajé, aya mi àtàtà, ojú ti mó |
| [02:34.43] | Ònà ọ'tun ti là, bóóde jàre |
| [02:39.13] | |
| [02:59.01] | Wá ká lọ s'ókè ìlera, k'ágbára d'ọ'tun |
| [03:03.10] | Ọjọ' òní ọjọ' àláfíà mà ló jẹ' |
| [03:08.37] | Wá ká lọ s'ọ'gbà ìtura b'óòrùn bá wọ' tán |
| [03:14.27] | Ká jó ká yọ', ijó alábùkún |
| [03:18.34] | Jomijòkè ọlọ'wọ'-aró, ẹni mi àtàtà, ọjó ti mó |
| [03:23.21] | Ojú ayé ti là, m'ásọ wò pàdé mi lóde |
| [03:28.17] | Òfaragbìjà, alápá-ajé, aya mi àtàtà, ojú ti mó |
| [03:33.22] | Ònà òtun ti là, bóóde jàre |
| [03:37.82] | Jomijòkè ọlọ'wọ'-aró, ẹni mi àtàtà, ọjó ti mọ' |
| [03:42.25] | Ojú ayé ti là, gbé'ra ko pàdé mi lóde |
| [03:47.55] | Òfaragbìjà, alápá-ajé, aya mi àtàtà, ojú ti mọ' |
| [03:51.81] | Ònà ọ'tun ti là, bóóde jàre |
| [03:58.26] |
| [00:15.46] | B mo b ti r' ni mi, in mi d n, ara mi y g g |
| [00:23.41] | Ma r' w r n ay, ma r' r n d nn, ma k' rin tuntun |
| [00:28.37] | B mo b ti r'' ni mi, in mi d n d l', ara mi y g g |
| [00:36.33] | Ma j' j ay, ma r' r n d nn |
| [00:41.48] | Jomij k l' w -ar, ni mi t t, j ti m' |
| [00:46.31] | Oj ay ti l, gb' ra ko p d mi l de |
| [00:51.44] | faragb j, al p -aj, aya mi t t, oj ti m' |
| [00:56.13] | ' n ' tun ti l, b de j re |
| [01:00.52] | W k l s' j d' ra, k m ' re b w l |
| [01:06.07] | j' n j al sel m l j' |
| [01:10.36] | W k l s' k d nn, k m' y b w l |
| [01:16.36] | j n j' ol yin |
| [01:20.71] | Jomij k l w -ar, ni mi t t, j' ti m |
| [01:25.58] | Oj ay ti l, m' w p d mi l de |
| [01:30.43] | faragb j, al p -aj, aya mi t t, oj ti m |
| [01:35.09] | n ' tun ti l, b de j re |
| [01:40.35] | |
| [01:59.84] | W k l s' d s gun, k f' w n k' re |
| [02:05.43] | j' n j' al el m l j' |
| [02:09.47] | W k l s'' d' gb, k' n s re f n wa |
| [02:15.29] | w wa t' ol bor ni |
| [02:20.01] | Jomij k l' w' -ar, ni mi t t, j' ti m' |
| [02:24.42] | Oj ay ti l, m ra ko p d mi l de |
| [02:29.82] | faragb j, al p -aj, aya mi t t, oj ti m |
| [02:34.43] | n ' tun ti l, b de j re |
| [02:39.13] | |
| [02:59.01] | W k l s' k lera, k' gb ra d'' tun |
| [03:03.10] | j' n j' l f m l j' |
| [03:08.37] | W k l s'' gb tura b' r n b w' t n |
| [03:14.27] | K j k y', ij al b k n |
| [03:18.34] | Jomij k l' w' -ar, ni mi t t, j ti m |
| [03:23.21] | Oj ay ti l, m' s w p d mi l de |
| [03:28.17] | faragb j, al p -aj, aya mi t t, oj ti m |
| [03:33.22] | n tun ti l, b de j re |
| [03:37.82] | Jomij k l' w' -ar, ni mi t t, j ti m' |
| [03:42.25] | Oj ay ti l, gb' ra ko p d mi l de |
| [03:47.55] | faragb j, al p -aj, aya mi t t, oj ti m' |
| [03:51.81] | n ' tun ti l, b de j re |