[00:42.93] Gbogbo àwọn tọ ní fẹ eto ilu [00:47.18] Gbogbo àwọn tọ n pero po le da [00:51.35] Gbogbo awon abaniṣe k'ọla k'ole dun [00:55.34] Gbogbo awon ọlọwọ atunṣe o [00:59.00] Bẹẹ riwọn l'óna ọja, è ma bami ke si wan ye (bẹẹ riwọn) [01:03.59] Bẹẹ riwọn l'oke odo, ẹ bam' bawọn sọrọ [01:07.23] Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) [01:09.59] Asiko ti to [01:11.65] Ọjọ taa wí yẹn o, o ti sunmọ [01:13.33] Ẹ jẹ a gbáradi [01:15.71] Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) [01:17.73] Asiko ti to, oh-oh [01:19.89] Ọjọ taa wí yẹn o, o ti dé tán [01:21.57] Ẹgbẹ a tuni to [01:23.56] [01:30.55] Gbogbo àwọn ìyá ọlọwọ itọju (ah-ah-ah-ah) [01:34.74] Gbogbo agba ọlọgbọn atọni s'ọna [01:38.71] Gbogbo awọn ti o fẹ ki're ko sọnu (ah-ah-ah-ah) [01:42.95] Gbogbo awọn ọdọ akíkanjú ẹni ire [01:46.70] Bẹẹ riwọn l'óna ọja, è ma bami ke si wan ye (bẹẹ riwọn) [01:50.98] Bẹẹ riwọn l'oke odo, ẹ bam' bawọn sọrọ [01:54.86] Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) [01:56.98] Asiko ti to [01:59.04] Ọjọ taa wí yẹn o, o ti sunmọ [02:00.78] Ẹ jẹ a gbáradi [02:03.12] Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) [02:05.25] Asiko ti to, oh-oh [02:07.46] Ọjọ taa wí yẹn o, o ti dé tán [02:08.81] Ẹgbẹ a tuni to [02:38.35] Bẹẹ riwọn l'óna ọja, è ma bami ke si wan ye (bẹẹ riwọn) [02:42.65] Bẹẹ riwọn l'oke odo, ẹ bam' bawọn sọrọ [02:46.33] Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) [02:48.68] Asiko ti to [02:50.74] Ọjọ taa wí yẹn o, o ti sunmọ [02:52.19] Ẹ jẹ a gbáradi [02:54.32] Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) [02:56.84] Asiko ti to, oh-oh [02:58.88] Ọjọ taa wí yẹn o, o ti dé tán [03:00.55] Ẹgbẹ a tuni to [03:03.03] Bẹẹ riwọn l'óna ọja, è ma bami ke si wan ye (bẹẹ riwọn) [03:07.03] Bẹẹ riwọn l'oke odo, ẹ bam' bawọn sọrọ [03:11.28] Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) [03:13.25] Asiko ti to [03:15.35] Ọjọ taa wí yẹn o, o ti sunmọ [03:16.87] Ẹ jẹ a gbáradi [03:19.32] Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) [03:21.21] Asiko ti to, oh-oh [03:23.51] Ọjọ taa wí yẹn o, o ti dé tán [03:25.24] Ẹgbẹ a tuni to [03:28.36]