[00:49.50] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o, yeah e [00:54.08] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (l'órí òkè, wọn tún gbe dé) [00:58.70] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (l'ọwọ' ìsàlẹ', wọn tún gbe dé o) [01:03.35] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (ké s'ọlọgbọn o, pọn tún ti dé o) [01:07.91] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (ké s'áwọn amòye, pọn tún ti dé o) [01:12.52] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o, yeah e [01:16.99] K'á ma fì'fẹ' lò, k'á ma wù'wà 're [01:21.52] K'á mú'ra s'óhun tí ó tún ìlú ṣe [01:25.93] K'á má ṣe sọ' irètí nù, k'á so'wọ' pọ' k'ó dára [01:31.30] ẸniỌbánkẹ', atọ'nisọ'nà ìyè [01:34.73] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o, yeah e [01:39.36] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (l'étí òkun o, wọn tún gbé dé) [01:44.21] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (ní'nú aginjù, wọn tún gbe dé o) [01:48.83] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (ké s'ọmọdé o, pọn tún ti dé) [01:53.52] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (ké s'áwọn àgbà, pọn tún ti dé) [01:58.15] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o, yeah e [02:01.92] Wọn ní k'ọmọ s'òtítọ', kó má ṣe s'àìgbọràn [02:04.46] Kò má ṣe ṣá'ìgbọràn, k'ó mú'ra sí iṣẹ' rẹ' l'áti kékeré [02:11.20] K'á má ṣe k'ẹgbẹkẹgbẹ, k'á má ma ṣè'gbéraga [02:16.80] ẸniỌbánkẹ', a kọmọ ní'wà ìrẹ'lẹ' [02:20.02] [03:05.86] Wọn ní k'a s'òtítọ', k'á ma wù'wà 're [03:10.99] K'á mú'ra s'óhun tí ó tún 'lẹ' yì ṣe [03:15.29] Wọn ní k'a f'òtẹ' s'ílẹ', k'a fì'wà ṣ'ọlá gẹngẹ [03:20.75] ẸniỌbánkẹ, a fún ni l'órò àgbà [03:24.14] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o, yeah e [03:29.04] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o (ní'bi kòrò, wọn tún gbe dé) [03:33.74] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o (ní gbangba o, wọn tún gbe dé o) [03:38.34] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (ké s'ọ'kùnrin o, pọn tún ti dé o) [03:42.99] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o (ké s'áwọn obìrin o, pọn tún ti dé) [03:47.65] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o, yeah e [03:52.21] Ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o, yeah e [04:00.27] Yeah e, ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o, yeah e [04:09.22] Yeah e, ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o, yeah e [04:18.73] Yeah e, ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o, yeah e [04:28.04] Yeah e, ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o [04:32.66]