[00:02.41] Kewu ní má fí wọlé [00:06.10] Kewu ní má fí wọlé ooh [00:10.32] Ilé ológo, ilé aláyọ' [00:14.09] Kewu ní má fí wọlé [00:16.86] Achalafuli jarafa karimu [00:19.12] Seribumi, serifa, seruku [00:20.93] Serimoka, serifa, kalisada deli ihh [00:25.35] Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh [00:28.10] (Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́) [00:34.81] Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh [00:37.95] (Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́) [00:41.91] [00:44.70] Ma da faliu, ma da selifa [00:47.24] Senseburi molaika, ibura kanka buriji madansimo seliu [00:52.22] Kò oloṣo tó dí slay mama, iṣẹ ló mà ṣe [00:56.07] Alert mí má dún, ojú yìn ló mà ṣé [00:59.31] Ilé o, gbọọrọ Olùwà, lórí rẹ má ṣe'un ire [01:03.03] Jẹ kó mà ṣẹgàn, kó má ṣábosì [01:05.02] Ọmọ ológo, mà gbérà [01:07.83] Elohi' o, ìwọ Àdàbà [01:11.72] Elohi' o, ìwọ Àdàbà ah [01:15.24] Àdàbà tó wà nínù ọgbà, Àdàbà Mímọ' ni [01:19.08] Àdàbà yí o, wọlé [01:22.70] Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh [01:25.78] (Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́) [01:28.30] [01:32.39] Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh [01:35.36] (Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́) [01:39.88] [01:42.64] B'ómi ṣé wọnú àgbọn mí, kò ṣeni tó yẹ [01:45.79] Ọlọrun o, motelimo, sarifa tali [01:49.84] Mà jẹ k'àyé bù mí pé camera mí ó dà [01:53.71] Mà jẹ k'àyé fí mí ṣẹ̀sín pé ìwà mí ó dà [01:57.49] Ọlọrun Mósè, M'Orimolade Tumolaṣe [02:01.35] Bàbá dàmí lóhùn aiye' mí ré, bà mí túnṣe [02:05.63] Elohi' o, ìwọ Àdàbà [02:09.42] Elohi' o, ìwọ Àdàbà ah [02:12.95] Àdàbà tó wà nínù ọgbà, Àdàbà Mímọ' ni [02:16.78] Àdàbà yí o, wọlé [02:20.25] Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh [02:23.48] (Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́) [02:27.93] [02:29.95] Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh [02:32.94] (Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́) [02:39.19] Ọmọ Cherubim, Seraphim [02:43.29] You gats to be prayerful [02:45.95] Torí pé, ibarasa lamalifu [02:48.65] Agbara luselifa [02:50.31] Seribumi, serifumi, elédè kewu [02:53.63] Ijiria falibu, saliabana kalifi [02:56.56] Mada selihu lona mefa [02:58.95] Mò pàṣẹ fowó inú afẹ'fẹ' [03:00.35] Kò má padà sínú afẹ'fẹ' mọ [03:02.61] À tí parí ẹ o [03:03.12]